Obara Oyeku
Owó lówọ́n ìyàwó ò wọ́n
Adifafun Ajé tíí se ìyá ògo
Ìgbàtí n ti Ilé òrun bowa sile ayé
Ẹbọ ni awo pe ki o se
Ó sì gbẹbọ lọpọlọpọ o rúbọ
Obara Òyèkú
Aje ni ìyá ògo
Aje ni baba tẹ́ni tẹ́ni
Obara Òyèkú ajé ni ìyá ògo
Aje ni baba agbeniga
Translation
It is money that scarce, getting a wife is not scarce
Casted Ifá divination for Ajé who is the mother of glory
When she was coming from the Heaven to the Earth
The Ifá priests advised her to perform sacrifices
She performed the sacrifices
Obara Òyèkú
1
1
60
The-father-of-Secrets retweeted
While my mate are sleeping or cuddling 🥺 I’m still here making herbs 🌿
IFA PRAYER FOR BREAKTHROUGH FROM CASE
Alẹ́lẹ́lẹ́ mo gbóhún dùrù
Mo gbóhùn dùrù tán
Mo tún gbọ́ dùkẹdùkẹ náà pẹ̀lú
Awọn niwọn sefafun Ọrunmila
Ifá ní ọjọ ti òhun ti dé ayé òhun kò dáràn rí
Ifá ní ẹ yàgò fún mi lọ́nà
Ẹ jẹ́ kí n ríbi lọ
Àkọnùn àkọnùn ni alákàn ńkọ àràn
Ọwọ mi bá ewé ọlalùgbàgbà ẹmọ̀sọ́ igi oko
Ọ̀ràn tí ẹ wí o
Ó lù gbàgbà ó fọ́
Ọwọ́ bewé alugbagba
Àpò kò lọ́wọ́
Àpò kò lẹ́sẹ̀
Ẹni ẹlẹ́ni níí tún ẹnu àpò se
Ọlọ̀bàrà tó gbé Ìdin pọ̀n tó lọ oko ejí
Ẹnìkan kò mu
1
1
58
The-father-of-Secrets retweeted
The 2nd Edition of the Ifáyẹmí Elebuibon Annual Symposium (IFEAS 2026) is ongoing at the Àbèjẹ́ Agbó Multipurpose Hall, Ààfin Ogbèyọ́nú in Òṣogbo, Osun State. The event honours the life and work of High Chief Ifáyẹmí Ayinde Elebuibon, the Àràbà Awo of Òṣogbo, celebrating his immense contributions to the preservation of Yorùbá culture and indigenous knowledge.
This year’s theme, "Answering Divine Calling in a Rapidly Evolving World: Lessons from Ifáyẹmí Ẹlẹ́buìbọn" (Jíjẹ́ Ìpè Irúnmọlẹ̀ ní Ayé Àìdúrólojúkan Òde Òní: Ẹ̀kọ́ Láti Ara Ifáyẹmí Ẹlẹ́buìbọn), addresses the modern challenge of maintaining spiritual devotion amid rapid global change. By analyzing Chief Ẹlẹ́buìbọn’s teachings, the symposium provides a vital space to explore how ancient spiritual wisdom continues to offer practical guidance for navigating contemporary life.
*facebook.com/share/v/1GXKP6j…*
📢 IFEAS 2026 IS TODAY! 🔥
Ẹ̀yin Babaláwo, Ìyáláwo, Omo Awo, Ìṣẹ̀ṣe devotees, scholars, àti gbogbo àwọn olólùfẹ́ ìsẹ̀se, this is a golden opportunity !
Today is the day we gather for the Ifáyẹmí Elébùíbón Annual Symposium (IFEAS 2026).
🪶 Àkórí Àpèrò:
Jijẹ́ Ipè Irúnmole ní Ayé Àìdúrólojúkan Ode Oní: Ẹ̀kọ́ Láti Ara Ifáyẹmí Elébùíbón.
This is not just another gathering. It is an opportunity to listen, learn, ask questions, share experience, deepen our knowledge of Ifá chanting, and receive wisdom from experience.
Come with an open mind.
Come with humility.
Come ready to learn.
Come ready to connect.
🔥 Today, we gather.
📚 Today, we learn.
🪶 Today, we strengthen the chain of knowledge.
Babaláwo Adépọ̀jù Adeboye Ọlaoluwa
National Organizing Secretary,
Isese Welfare Association (IWA)
Aka Ìṣẹ̀ṣe Assembly.
The-father-of-Secrets retweeted
E kaaro omo Alagbo yin ti de oo🗣️🗣️🌿
As Una no gree buy online again, na to dey hawk remain ooo
Booda Ola, Booda Lati, ati Aunty Amuda, e pade mi ni isale street .
Na there e dey happen !!!
May Ifa bring back our lost opportunities in this New Month.
Ifá ní kánimọ́lé kánimọ́lé bí eji alẹ́
Kùtùkùtù ni Ìká ti ká Ìrosùn mọ́lé nítorí ẹdan eku nítorí ẹdan ẹja
Awon lodifafun Orunmila níjó tí Òsùn baba rẹ nùnhúnnùn lọ
Branch at someone's house without prior notice is like rain falling in the night
Very early in the morning was when Ika branched at the Ìrosùn house because of sacred rat and sacred fish
Casted Ifá divination for Orunmila when his father's Òsùn lost
1
1
39
Akú Ọ̀sẹ̀ Awo o!
May Ifá accept our offerings and prayers.
Ifá ní pàńkàrà wówòwó awo Adabọ
Difafun Adabọ tíí se òjíṣẹ́ Olodumare
Ẹbọ ni awo pe ki o rù ẹbọ ni awo pe ki o ṣe
Kínni yóó jẹ kí ẹbọ de ọ̀run
Adabọ jọwọ jẹ ki ẹbọ dà fún ẹlẹ́bọ
Adabọ
The-father-of-Secrets retweeted
Osun State Government Please help rectify this before osun festival 🙏🏿
The Ifá Priests advised him to perform sacrifices
What is going to take the sacrifices to the heaven?
It is Adabọ that will make sacrifices to be accepted in the heaven for the performer (ẹlẹ́bọ)
Adabọ
Deliver the message of wealth
Deliver the message of partners
1
1
47












