Replying to @Wizarab10
It depends on how it was prepared, if unfortunately your first experience was not with the right bole, it's gonna suck but when done right.....yeah, it slaps
68
Ọmọ olù nla,
Ọmọ ọrẹgbe,
Ọmọ Amororo bi ilẹkẹ,
Ọmọ Akesan baálé ọjà,
Akesan níí dádé, aya rẹ níí d'oja.
Iperu-Remo.
#Ogun@50
69








